2 Àwọn Ọba 24:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nígbà ayé Jèhóákímù, Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì wá gbéjà kò ó, Jèhóákímù sì fi ọdún mẹ́ta ṣe ìránṣẹ́ fún un. Àmọ́, ó yí pa dà, ó sì ṣọ̀tẹ̀. 2 Kíróníkà 36:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ni Jèhóákímù+ nígbà tó jọba, ọdún mọ́kànlá (11) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Ó ń ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀.+
24 Nígbà ayé Jèhóákímù, Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì wá gbéjà kò ó, Jèhóákímù sì fi ọdún mẹ́ta ṣe ìránṣẹ́ fún un. Àmọ́, ó yí pa dà, ó sì ṣọ̀tẹ̀.
5 Ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ni Jèhóákímù+ nígbà tó jọba, ọdún mọ́kànlá (11) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Ó ń ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀.+