2 Kíróníkà 36:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹni ọdún mọ́kànlélógún (21) ni Sedekáyà+ nígbà tó jọba, ọdún mọ́kànlá (11) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ 2 Kíróníkà 36:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ó tún ṣọ̀tẹ̀ sí Ọba Nebukadinésárì,+ ẹni tó mú kó fi Ọlọ́run búra, ó ya olórí kunkun* àti ọlọ́kàn líle, ó kọ̀, kò yíjú sí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì. Ìsíkíẹ́lì 17:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àmọ́ níkẹyìn, ọba náà ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ ó rán àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ sí Íjíbítì, kí wọ́n lè fún un ní àwọn ẹṣin+ àti ọmọ ogun púpọ̀.+ Ṣé ó máa ṣàṣeyọrí? Ǹjẹ́ ẹni tó ń ṣe nǹkan wọ̀nyí á bọ́ lọ́wọ́ ìyà? Ṣé ó lè da májẹ̀mú kó sì mú un jẹ?’+
11 Ẹni ọdún mọ́kànlélógún (21) ni Sedekáyà+ nígbà tó jọba, ọdún mọ́kànlá (11) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+
13 Ó tún ṣọ̀tẹ̀ sí Ọba Nebukadinésárì,+ ẹni tó mú kó fi Ọlọ́run búra, ó ya olórí kunkun* àti ọlọ́kàn líle, ó kọ̀, kò yíjú sí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì.
15 Àmọ́ níkẹyìn, ọba náà ṣọ̀tẹ̀ sí i,+ ó rán àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ sí Íjíbítì, kí wọ́n lè fún un ní àwọn ẹṣin+ àti ọmọ ogun púpọ̀.+ Ṣé ó máa ṣàṣeyọrí? Ǹjẹ́ ẹni tó ń ṣe nǹkan wọ̀nyí á bọ́ lọ́wọ́ ìyà? Ṣé ó lè da májẹ̀mú kó sì mú un jẹ?’+