- 
	                        
            
            Àìsáyà 48:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 Torí mo mọ bí o ṣe lágídí tó, Pé irin ni iṣan ọrùn rẹ àti pé bàbà ni iwájú orí rẹ,+ - 
	                        
            
            Jeremáyà 5:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        23 Ṣùgbọ́n àwọn èèyàn yìí jẹ́ alágídí ọkàn, wọ́n sì ya ọlọ̀tẹ̀; Wọ́n fi ọ̀nà mi sílẹ̀, wọ́n sì bá ọ̀nà wọn lọ.+ 
 
- 
                                        
 
- 
	                        
            
            
 
-