ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 30:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 “Ṣùgbọ́n màá mú ọ lára dá, màá sì wo ọgbẹ́ rẹ sàn,”+ ni Jèhófà wí,

      “Bí wọ́n tiẹ̀ pè ọ́ ní ẹni ìtanù:

      ‘Síónì, tí ẹnikẹ́ni kò fẹ́.’”+

  • Jeremáyà 33:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí nípa àwọn ilé tó wà ní ìlú yìí àti ilé àwọn ọba Júdà tí wọ́n wó lulẹ̀ nípasẹ̀ àwọn òkìtì tí wọ́n mọ láti dó ti ìlú yìí àti nípasẹ̀ idà,+

  • Jeremáyà 33:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 ‘Wò ó, màá mú kí ara rẹ̀ kọ́fẹ, màá sì fún un ní ìlera,+ màá mú wọn lára dá, màá sì fún wọn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àlàáfíà àti òtítọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́