Jeremáyà 6:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ìwọ ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi,Wọ aṣọ ọ̀fọ̀,*+ kí o sì yí nínú eérú. Ṣọ̀fọ̀ bí ẹni tí ọmọkùnrin rẹ̀ kan ṣoṣo kú, kí o sì sunkún gidigidi,+Torí lójijì ni apanirun máa dé bá wa.+ Jeremáyà 14:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Sọ ọ̀rọ̀ yìí fún wọn pé,‘Kí omijé ṣàn ní ojú mi tọ̀sántòru, kí ó má sì dá,+Nítorí wọ́n ti lu wúńdíá àwọn èèyàn mi ní àlùbolẹ̀,+Wọ́n sì dá ọgbẹ́ sí i lára yánnayànna.
26 Ìwọ ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi,Wọ aṣọ ọ̀fọ̀,*+ kí o sì yí nínú eérú. Ṣọ̀fọ̀ bí ẹni tí ọmọkùnrin rẹ̀ kan ṣoṣo kú, kí o sì sunkún gidigidi,+Torí lójijì ni apanirun máa dé bá wa.+
17 “Sọ ọ̀rọ̀ yìí fún wọn pé,‘Kí omijé ṣàn ní ojú mi tọ̀sántòru, kí ó má sì dá,+Nítorí wọ́n ti lu wúńdíá àwọn èèyàn mi ní àlùbolẹ̀,+Wọ́n sì dá ọgbẹ́ sí i lára yánnayànna.