-
2 Àwọn Ọba 17:6, 7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ní ọdún kẹsàn-án Hóṣéà, ọba Ásíríà gba Samáríà.+ Ó wá kó àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ní ìgbèkùn+ lọ sí Ásíríà, ó sì mú kí wọ́n máa gbé ní Hálà àti ní Hábórì níbi odò Gósánì+ àti ní àwọn ìlú àwọn ará Mídíà.+
7 Ohun tó fa èyí ni pé àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ṣẹ̀ sí Jèhófà Ọlọ́run wọn, ẹni tó mú wọn jáde kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, kúrò lábẹ́ àṣẹ Fáráò ọba Íjíbítì.+ Wọ́n sin* àwọn ọlọ́run míì,+
-