ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 80:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 O mú kí àjàrà+ kan kúrò ní Íjíbítì.

      O lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde, o sì gbin àjàrà náà.+

  • Àìsáyà 5:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Jọ̀ọ́, jẹ́ kí n kọrin fún ẹni tí mo fẹ́ràn,

      Orin tó dá lórí ẹni tí mo nífẹ̀ẹ́ àti ọgbà àjàrà rẹ̀.+

      Ẹni tí mo fẹ́ràn ní ọgbà àjàrà kan síbi òkè tó lọ́ràá.

  • Àìsáyà 5:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Torí pé ilé Ísírẹ́lì ni ọgbà àjàrà Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun;+

      Àwọn èèyàn Júdà sì ni oko* tó fẹ́ràn.

      Ó ń retí ìdájọ́ òdodo,+

      Àmọ́ wò ó! ìrẹ́jẹ ló wà;

      Ó ń retí òdodo,

      Àmọ́ wò ó! igbe ìdààmú ló wà.”+

  • Jeremáyà 6:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Àwọn olùṣọ́ àgùntàn àti agbo ẹran wọn yóò wá.

      Wọ́n á pa àgọ́ wọn yí i ká,+

      Kálukú wọn á máa kó agbo ẹran wọn jẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́