Léfítíkù 26:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Èmi yóò tú yín ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ màá sì fa idà yọ látinú àkọ̀ láti lé yín bá;+ ilẹ̀ yín yóò di ahoro,+ àwọn ìlú yín yóò sì pa run. Jeremáyà 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Bí wọ́n bá sì bi ọ́ pé, ‘Kí ló máa ṣẹlẹ̀ sí wa?’ kí o sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Àjàkálẹ̀ àrùn máa pa àwọn kan lára yín! Idà máa pa àwọn kan lára yín!+ Ìyàn máa pa àwọn míì lára yín! Àwọn kan lára yín sì máa lọ sóko ẹrú!”’+
33 Èmi yóò tú yín ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ màá sì fa idà yọ látinú àkọ̀ láti lé yín bá;+ ilẹ̀ yín yóò di ahoro,+ àwọn ìlú yín yóò sì pa run.
2 Bí wọ́n bá sì bi ọ́ pé, ‘Kí ló máa ṣẹlẹ̀ sí wa?’ kí o sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Àjàkálẹ̀ àrùn máa pa àwọn kan lára yín! Idà máa pa àwọn kan lára yín!+ Ìyàn máa pa àwọn míì lára yín! Àwọn kan lára yín sì máa lọ sóko ẹrú!”’+