ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 36:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ọ̀dọ̀ rẹ ni orísun ìyè wà;+

      Ipasẹ̀ ìmọ́lẹ̀ rẹ ni a fi lè rí ìmọ́lẹ̀.+

  • Jeremáyà 17:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Jèhófà, ìwọ ni ìrètí Ísírẹ́lì,

      Ojú máa ti gbogbo àwọn tó bá fi ọ́ sílẹ̀.

      Àwọn tó bá pẹ̀yìn dà lọ́dọ̀ rẹ* ni a ó kọ orúkọ wọn sórí eruku ilẹ̀,+

      Torí pé wọ́n ti fi Jèhófà sílẹ̀, ẹni tó jẹ́ orísun omi ìyè.+

  • Ìfihàn 22:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ó wá fi odò omi ìyè+ kan hàn mí, tó mọ́ rekete bíi kírísítálì, tó ń ṣàn jáde láti ibi ìtẹ́ Ọlọ́run àti ti Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà  +

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́