Jeremáyà 7:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Ní tìrẹ, má ṣe gbàdúrà nítorí àwọn èèyàn yìí. Má ṣe sunkún tàbí kí o gbàdúrà tàbí kí o bẹ̀ mí nítorí wọn,+ torí mi ò ní fetí sí ọ.+ Jeremáyà 11:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Ní tìrẹ,* má ṣe gbàdúrà nítorí àwọn èèyàn yìí. Má sì sunkún nítorí wọn tàbí kí o gbàdúrà fún wọn,+ torí mi ò ní fetí sílẹ̀ tí wọ́n bá ń ké pè mí nígbà àjálù wọn.
16 “Ní tìrẹ, má ṣe gbàdúrà nítorí àwọn èèyàn yìí. Má ṣe sunkún tàbí kí o gbàdúrà tàbí kí o bẹ̀ mí nítorí wọn,+ torí mi ò ní fetí sí ọ.+
14 “Ní tìrẹ,* má ṣe gbàdúrà nítorí àwọn èèyàn yìí. Má sì sunkún nítorí wọn tàbí kí o gbàdúrà fún wọn,+ torí mi ò ní fetí sílẹ̀ tí wọ́n bá ń ké pè mí nígbà àjálù wọn.