- 
	                        
            
            Jeremáyà 18:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        23 Ṣùgbọ́n, ìwọ Jèhófà, O mọ gbogbo ètekéte wọn dáadáa, bí wọ́n ṣe fẹ́ pa mí.+ Má bo àṣìṣe wọn, Má sì pa ẹ̀ṣẹ̀ wọn rẹ́ kúrò níwájú rẹ. 
 
-