Jeremáyà 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí náà, ìbínú Jèhófà ti kún inú mi,Ara mi ò sì gbà á mọ́.”+ “Dà á sórí ọmọ tó wà lójú ọ̀nà,+Sórí àwọn àwùjọ ọ̀dọ́kùnrin tó kóra jọ. Gbogbo wọn ni ọwọ́ máa tẹ̀, láìyọ ọkùnrin kan àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀,Àwọn àgbàlagbà pẹ̀lú àwọn arúgbó.*+ Émọ́sì 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Kìnnìún ti ké ramúramù!+ Ta ni kò ní bẹ̀rù? Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti sọ̀rọ̀! Ta ni kò ní sọ tẹ́lẹ̀?’+ Ìṣe 4:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àmọ́, Pétérù àti Jòhánù fún wọn lésì pé: “Ẹ̀yin náà ẹ sọ, tó bá tọ́ lójú Ọlọ́run pé ká fetí sí yín dípò ká fetí sí Ọlọ́run. 20 Àmọ́ ní tiwa, a ò lè ṣàì sọ ohun tí a ti rí tí a sì ti gbọ́.”+
11 Torí náà, ìbínú Jèhófà ti kún inú mi,Ara mi ò sì gbà á mọ́.”+ “Dà á sórí ọmọ tó wà lójú ọ̀nà,+Sórí àwọn àwùjọ ọ̀dọ́kùnrin tó kóra jọ. Gbogbo wọn ni ọwọ́ máa tẹ̀, láìyọ ọkùnrin kan àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀,Àwọn àgbàlagbà pẹ̀lú àwọn arúgbó.*+
8 Kìnnìún ti ké ramúramù!+ Ta ni kò ní bẹ̀rù? Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti sọ̀rọ̀! Ta ni kò ní sọ tẹ́lẹ̀?’+
19 Àmọ́, Pétérù àti Jòhánù fún wọn lésì pé: “Ẹ̀yin náà ẹ sọ, tó bá tọ́ lójú Ọlọ́run pé ká fetí sí yín dípò ká fetí sí Ọlọ́run. 20 Àmọ́ ní tiwa, a ò lè ṣàì sọ ohun tí a ti rí tí a sì ti gbọ́.”+