Àìsáyà 24:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ilẹ̀ náà ń ṣọ̀fọ̀;*+ ó ń joro. Ilẹ̀ tó ń méso jáde ò lọ́ràá mọ́; ó ti ń ṣá. Àwọn gbajúmọ̀ ilẹ̀ náà ti rẹ̀ dà nù. Jóẹ́lì 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wọ́n ti pa oko run, ilẹ̀ sì ń ṣọ̀fọ̀;+Wọ́n ti run ọkà, wáìnì tuntun ti gbẹ táútáú, òróró sì ti tán.+
4 Ilẹ̀ náà ń ṣọ̀fọ̀;*+ ó ń joro. Ilẹ̀ tó ń méso jáde ò lọ́ràá mọ́; ó ti ń ṣá. Àwọn gbajúmọ̀ ilẹ̀ náà ti rẹ̀ dà nù.
10 Wọ́n ti pa oko run, ilẹ̀ sì ń ṣọ̀fọ̀;+Wọ́n ti run ọkà, wáìnì tuntun ti gbẹ táútáú, òróró sì ti tán.+