ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 85:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 85 Jèhófà, o ti ṣojú rere sí ilẹ̀ rẹ;+

      O mú àwọn tí wọ́n kó lẹ́rú+ lára Jékọ́bù pa dà wá.

  • Jeremáyà 24:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ojú mi yóò wà lára wọn láti ṣe wọ́n lóore, màá sì mú kí wọ́n pa dà sí ilẹ̀ yìí.+ Màá gbé wọn ró, mi ò sì ní ya wọ́n lulẹ̀, màá gbìn wọ́n, mi ò sì ní fà wọ́n tu.+

  • Jeremáyà 29:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Tó bá ti pé àádọ́rin (70) ọdún tí ẹ ti wà ní Bábílónì, màá yí ojú mi sí yín,+ màá sì mú ìlérí mi ṣẹ láti mú yín pa dà wá sí ibí yìí.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́