- 
	                        
            
            Jeremáyà 50:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        14 Ẹ jáde lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti gbógun ti Bábílónì láti ibi gbogbo, Gbogbo ẹ̀yin tó ń tẹ* ọrun. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jeremáyà 50:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        27 Pa gbogbo akọ ọmọ màlúù rẹ̀ ní ìpakúpa;+ Kí wọ́n sọ̀ kalẹ̀ lọ sí ibi tí wọ́n ti máa pa wọ́n. Wọ́n gbé, nítorí ọjọ́ wọn ti dé, Àkókò ìyà wọn! 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Dáníẹ́lì 5:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        30 Òru ọjọ́ yẹn gan-an ni wọ́n pa Bẹliṣásárì, ọba àwọn ará Kálídíà.+ 
 
-