Àìsáyà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Tí kì í bá ṣe pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun dá díẹ̀ nínú wa sí,À bá ti dà bíi Sódómù gẹ́lẹ́,À bá sì ti jọ Gòmórà.+ Jeremáyà 23:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Ìgbà náà ni màá kó àwọn tó ṣẹ́ kù lára àgùntàn mi jọ láti gbogbo ilẹ̀ tí mo fọ́n wọn ká sí,+ màá sì mú wọn pa dà wá sí ibi ìjẹko wọn,+ wọ́n á máa bímọ, wọ́n á sì di púpọ̀.+ Jóẹ́lì 2:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Gbogbo ẹni tó bá ń ké pe orúkọ Jèhófà yóò sì rí ìgbàlà;+Torí àwọn tó sá àsálà yóò wà ní Òkè Síónì àti ní Jerúsálẹ́mù+ bí Jèhófà ṣe sọ,Àwọn tó là á já tí Jèhófà pè.”
9 Tí kì í bá ṣe pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun dá díẹ̀ nínú wa sí,À bá ti dà bíi Sódómù gẹ́lẹ́,À bá sì ti jọ Gòmórà.+
3 “Ìgbà náà ni màá kó àwọn tó ṣẹ́ kù lára àgùntàn mi jọ láti gbogbo ilẹ̀ tí mo fọ́n wọn ká sí,+ màá sì mú wọn pa dà wá sí ibi ìjẹko wọn,+ wọ́n á máa bímọ, wọ́n á sì di púpọ̀.+
32 Gbogbo ẹni tó bá ń ké pe orúkọ Jèhófà yóò sì rí ìgbàlà;+Torí àwọn tó sá àsálà yóò wà ní Òkè Síónì àti ní Jerúsálẹ́mù+ bí Jèhófà ṣe sọ,Àwọn tó là á já tí Jèhófà pè.”