Jeremáyà 50:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Ní àwọn ọjọ́ yẹn àti ní àkókò yẹn,” ni Jèhófà wí, “àwọn èèyàn Ísírẹ́lì àti àwọn èèyàn Júdà máa kóra jọ.+ Wọ́n á máa sunkún bí wọ́n ṣe ń rìn lọ,+ wọ́n á sì jọ máa wá Jèhófà Ọlọ́run wọn.+
4 “Ní àwọn ọjọ́ yẹn àti ní àkókò yẹn,” ni Jèhófà wí, “àwọn èèyàn Ísírẹ́lì àti àwọn èèyàn Júdà máa kóra jọ.+ Wọ́n á máa sunkún bí wọ́n ṣe ń rìn lọ,+ wọ́n á sì jọ máa wá Jèhófà Ọlọ́run wọn.+