Sáàmù 102:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jèhófà máa tún Síónì kọ́;+Á fara hàn nínú ògo rẹ̀.+ Sáàmù 147:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà ń kọ́ Jerúsálẹ́mù;+Ó ń kó àwọn tí wọ́n fọ́n ká lára Ísírẹ́lì jọ.+ Jeremáyà 24:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ojú mi yóò wà lára wọn láti ṣe wọ́n lóore, màá sì mú kí wọ́n pa dà sí ilẹ̀ yìí.+ Màá gbé wọn ró, mi ò sì ní ya wọ́n lulẹ̀, màá gbìn wọ́n, mi ò sì ní fà wọ́n tu.+
6 Ojú mi yóò wà lára wọn láti ṣe wọ́n lóore, màá sì mú kí wọ́n pa dà sí ilẹ̀ yìí.+ Màá gbé wọn ró, mi ò sì ní ya wọ́n lulẹ̀, màá gbìn wọ́n, mi ò sì ní fà wọ́n tu.+