ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 3:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Lọ, kí o sì kéde ọ̀rọ̀ wọ̀nyí fún àríwá pé:+

      “‘“Pa dà, ìwọ Ísírẹ́lì ọ̀dàlẹ̀,” ni Jèhófà wí.’+ ‘“Mi ò ní wò ọ́ tìbínútìbínú,*+ nítorí adúróṣinṣin ni mí,” ni Jèhófà wí.’ ‘“Mi ò sì ní máa bínú títí láé.

  • Jeremáyà 31:37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “‘Àyàfi bí a bá lè díwọ̀n ọ̀run lókè, tí a sì lè wá ìpìlẹ̀ ayé kàn nísàlẹ̀, ni màá tó kọ gbogbo àtọmọdọ́mọ Ísírẹ́lì sílẹ̀ torí àwọn ohun tí wọ́n ti ṣe,’ ni Jèhófà wí.”+

  • Jeremáyà 32:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 Màá sì bá wọn dá májẹ̀mú tó máa wà títí láé,+ pé mi ò ní jáwọ́ nínú ṣíṣe rere fún wọn;+ màá fi ìbẹ̀rù mi sínú ọkàn wọn, kí wọ́n má bàa kúrò lọ́dọ̀ mi.+

  • Míkà 7:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ta ló dà bí rẹ, Ọlọ́run,

      Tó ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ jini, tó sì ń gbójú fo ìṣìnà+ àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún rẹ̀?+

      Kò ní máa bínú lọ títí láé,

      Torí inú rẹ̀ máa ń dùn sí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́