Sáàmù 137:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà, jọ̀wọ́ rántíOhun tí àwọn ọmọ Édómù sọ lọ́jọ́ tí Jerúsálẹ́mù ṣubú, wọ́n ní: “Ẹ wó o palẹ̀! Ẹ wó o palẹ̀ dé ìpìlẹ̀ rẹ̀!”+ Ìdárò 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Gbogbo ọ̀tá rẹ ti la ẹnu wọn sí ọ. Wọ́n ń súfèé, wọ́n sì wa eyín pọ̀, wọ́n ń sọ pé: “A ti gbé e mì.+ Ọjọ́ tí à ń retí nìyí! + Ó ti dé, a sì ti rí i!”+
7 Jèhófà, jọ̀wọ́ rántíOhun tí àwọn ọmọ Édómù sọ lọ́jọ́ tí Jerúsálẹ́mù ṣubú, wọ́n ní: “Ẹ wó o palẹ̀! Ẹ wó o palẹ̀ dé ìpìlẹ̀ rẹ̀!”+
16 Gbogbo ọ̀tá rẹ ti la ẹnu wọn sí ọ. Wọ́n ń súfèé, wọ́n sì wa eyín pọ̀, wọ́n ń sọ pé: “A ti gbé e mì.+ Ọjọ́ tí à ń retí nìyí! + Ó ti dé, a sì ti rí i!”+