Diutarónómì 32:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí ìbínú mi ti mú kí iná+ sọ,Ó sì máa jó wọnú Isà Òkú,*+Ó máa jó ayé àti èso rẹ̀ run,Iná á sì ran ìpìlẹ̀ àwọn òkè. 2 Àwọn Ọba 25:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó dáná sun ilé Jèhófà+ àti ilé* ọba+ pẹ̀lú gbogbo ilé tó wà ní Jerúsálẹ́mù;+ ó tún sun ilé gbogbo àwọn ẹni ńlá.+ 10 Gbogbo ògiri tó yí Jerúsálẹ́mù ká ni gbogbo àwọn ọmọ ogun Kálídíà tó wà pẹ̀lú olórí ẹ̀ṣọ́ wó lulẹ̀.+
22 Torí ìbínú mi ti mú kí iná+ sọ,Ó sì máa jó wọnú Isà Òkú,*+Ó máa jó ayé àti èso rẹ̀ run,Iná á sì ran ìpìlẹ̀ àwọn òkè.
9 Ó dáná sun ilé Jèhófà+ àti ilé* ọba+ pẹ̀lú gbogbo ilé tó wà ní Jerúsálẹ́mù;+ ó tún sun ilé gbogbo àwọn ẹni ńlá.+ 10 Gbogbo ògiri tó yí Jerúsálẹ́mù ká ni gbogbo àwọn ọmọ ogun Kálídíà tó wà pẹ̀lú olórí ẹ̀ṣọ́ wó lulẹ̀.+