-
1 Sámúẹ́lì 12:14, 15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Tí ẹ bá bẹ̀rù Jèhófà,+ tí ẹ sì ń sìn ín,+ tí ẹ̀ ń ṣègbọràn sí ohùn rẹ̀,+ tí ẹ kò sì ṣọ̀tẹ̀ sí àṣẹ Jèhófà, tí ẹ̀yin àti ọba tí ó jẹ lórí yín ń tẹ̀ lé Jèhófà Ọlọ́run yín, á dáa fún yín. 15 Àmọ́ tí ẹ kò bá ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà, tí ẹ kò sì pa àṣẹ Jèhófà mọ́, ọwọ́ Jèhófà yóò le mọ́ ẹ̀yin àti àwọn bàbá yín.+
-