ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 74:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Kò sí àmì kankan tí a rí;

      Kò sí wòlíì kankan mọ́,

      Kò sì sí ẹnì kankan nínú wa tó mọ bí èyí ṣe máa pẹ́ tó.

  • Jeremáyà 23:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí:

      “Ẹ má fetí sí ọ̀rọ̀ àwọn wòlíì tó ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ fún yín.+

      Wọ́n ń tàn yín ni.*

      Ìran tó wá láti inú ọkàn wọn ni wọ́n ń sọ,+

      Kì í ṣe láti ẹnu Jèhófà.+

  • Ìsíkíẹ́lì 7:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Àjálù á ré lu àjálù, wọ́n á gbọ́ ìròyìn kan tẹ̀ lé òmíràn, àwọn èèyàn á wá ìran lọ sọ́dọ̀ wòlíì,+ àmọ́ òfin* yóò ṣègbé lọ́dọ̀ àlùfáà, ìmọ̀ràn ò sì ní sí lẹ́nu àwọn àgbààgbà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́