-
Sáàmù 74:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Kò sí àmì kankan tí a rí;
Kò sí wòlíì kankan mọ́,
Kò sì sí ẹnì kankan nínú wa tó mọ bí èyí ṣe máa pẹ́ tó.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 20:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 “Ọmọ èèyàn, bá àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀, kí o sì sọ fún wọn pé, ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Ṣé ọ̀dọ̀ mi lẹ ti fẹ́ wádìí ọ̀rọ̀ ni? ‘Bí mo ti wà láàyè, mi ò ní dá yín lóhùn,’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”’
-