Jẹ́nẹ́sísì 27:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Ṣùgbọ́n Ísọ̀ di Jékọ́bù sínú torí pé bàbá rẹ̀ ti súre fún un,+ Ísọ̀ sì ń sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé: “Ọjọ́ tí a máa ṣọ̀fọ̀ bàbá mi ti ń sún mọ́lé.+ Lẹ́yìn náà, ṣe ni màá pa Jékọ́bù àbúrò mi.” Émọ́sì 1:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta Édómù+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí ó fi idà lépa arákùnrin rẹ̀,+Àti nítorí pé ó kọ̀ láti ṣàánú rẹ̀;Ó ń fi ìbínú rẹ̀ fà wọ́n ya láìdáwọ́ dúró,Kò sì yéé bínú sí wọn.+
41 Ṣùgbọ́n Ísọ̀ di Jékọ́bù sínú torí pé bàbá rẹ̀ ti súre fún un,+ Ísọ̀ sì ń sọ lọ́kàn ara rẹ̀ pé: “Ọjọ́ tí a máa ṣọ̀fọ̀ bàbá mi ti ń sún mọ́lé.+ Lẹ́yìn náà, ṣe ni màá pa Jékọ́bù àbúrò mi.”
11 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta Édómù+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí ó fi idà lépa arákùnrin rẹ̀,+Àti nítorí pé ó kọ̀ láti ṣàánú rẹ̀;Ó ń fi ìbínú rẹ̀ fà wọ́n ya láìdáwọ́ dúró,Kò sì yéé bínú sí wọn.+