Sáàmù 137:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà, jọ̀wọ́ rántíOhun tí àwọn ọmọ Édómù sọ lọ́jọ́ tí Jerúsálẹ́mù ṣubú, wọ́n ní: “Ẹ wó o palẹ̀! Ẹ wó o palẹ̀ dé ìpìlẹ̀ rẹ̀!”+ Ọbadáyà 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nítorí ìwà ìkà tí o hù sí Jékọ́bù ọmọ ìyá rẹ,+Ojú yóò tì ọ́,+Ìwọ yóò sì ṣègbé títí láé.+
7 Jèhófà, jọ̀wọ́ rántíOhun tí àwọn ọmọ Édómù sọ lọ́jọ́ tí Jerúsálẹ́mù ṣubú, wọ́n ní: “Ẹ wó o palẹ̀! Ẹ wó o palẹ̀ dé ìpìlẹ̀ rẹ̀!”+