Ìdárò 4:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ìyà tí a fi jẹ* ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi pọ̀ ju ìyà ẹ̀ṣẹ̀ tí a fi jẹ* Sódómù lọ,+Tí a ṣẹ́gun ní ìṣẹ́jú kan, láìsí ẹnì kankan tó ràn án lọ́wọ́.+ Dáníẹ́lì 9:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ó ti ṣe ohun tó sọ lòdì sí àwa+ àti àwọn alákòóso wa tí wọ́n jọba lé wa lórí,* torí ó mú kí àjálù ńlá ṣẹlẹ̀ sí wa; ohunkóhun ò ṣẹlẹ̀ rí lábẹ́ gbogbo ọ̀run bí èyí tó ṣẹlẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù.+
6 Ìyà tí a fi jẹ* ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi pọ̀ ju ìyà ẹ̀ṣẹ̀ tí a fi jẹ* Sódómù lọ,+Tí a ṣẹ́gun ní ìṣẹ́jú kan, láìsí ẹnì kankan tó ràn án lọ́wọ́.+
12 Ó ti ṣe ohun tó sọ lòdì sí àwa+ àti àwọn alákòóso wa tí wọ́n jọba lé wa lórí,* torí ó mú kí àjálù ńlá ṣẹlẹ̀ sí wa; ohunkóhun ò ṣẹlẹ̀ rí lábẹ́ gbogbo ọ̀run bí èyí tó ṣẹlẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù.+