Jeremáyà 30:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Ẹ ó di èèyàn mi,+ màá sì di Ọlọ́run yín.”+ Ìsíkíẹ́lì 37:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Wọn yóò máa gbé lórí ilẹ̀ tí mo fún Jékọ́bù ìránṣẹ́ mi, ibi tí àwọn baba ńlá yín gbé,+ wọn yóò sì máa gbé lórí rẹ̀ títí láé,+ àwọn àti àwọn ọmọ* wọn àti àwọn ọmọ ọmọ wọn;+ Dáfídì ìránṣẹ́ mi ni yóò sì jẹ́ ìjòyè* wọn títí láé.+ Ìsíkíẹ́lì 37:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Àgọ́* mi yóò wà pẹ̀lú* wọn, èmi yóò di Ọlọ́run wọn, wọn yóò sì di èèyàn mi.+
25 Wọn yóò máa gbé lórí ilẹ̀ tí mo fún Jékọ́bù ìránṣẹ́ mi, ibi tí àwọn baba ńlá yín gbé,+ wọn yóò sì máa gbé lórí rẹ̀ títí láé,+ àwọn àti àwọn ọmọ* wọn àti àwọn ọmọ ọmọ wọn;+ Dáfídì ìránṣẹ́ mi ni yóò sì jẹ́ ìjòyè* wọn títí láé.+