Ìsíkíẹ́lì 38:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Èmi yóò fi àjàkálẹ̀ àrùn+ àti ikú dá a lẹ́jọ́; èmi yóò mú kí òjò àrọ̀ọ̀rọ̀dá, òkúta yìnyín,+ iná+ àti imí ọjọ́+ rọ̀ lé òun àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ lórí àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn tó wà pẹ̀lú rẹ̀.+
22 Èmi yóò fi àjàkálẹ̀ àrùn+ àti ikú dá a lẹ́jọ́; èmi yóò mú kí òjò àrọ̀ọ̀rọ̀dá, òkúta yìnyín,+ iná+ àti imí ọjọ́+ rọ̀ lé òun àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ lórí àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn tó wà pẹ̀lú rẹ̀.+