20 Gígùn yàrá inú lọ́hùn-ún náà jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́;+ ó sì fi ògidì wúrà bò ó; ó fi igi kédárì bo pẹpẹ náà.+
8 Ó ṣe apá* Ibi Mímọ́ Jù Lọ,+ gígùn rẹ̀ bá fífẹ̀ ilé náà mu, ó jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́, fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́. Ó fi ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (600) tálẹ́ńtì* wúrà tó dára bò ó.+