Ìsíkíẹ́lì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn ohun tó dà bí ẹ̀dá alààyè mẹ́rin+ wà nínú rẹ̀, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn sì rí bí èèyàn. Ìsíkíẹ́lì 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bí ojú wọn ṣe rí nìyí: Ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ní ojú èèyàn, ojú kìnnìún+ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀tún, ojú akọ màlúù+ lẹ́gbẹ̀ẹ́ òsì, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn sì ní ojú+ idì.+ Ìfihàn 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ̀dá alààyè àkọ́kọ́ dà bíi kìnnìún,+ ẹ̀dá alààyè kejì dà bí akọ ọmọ màlúù,+ ẹ̀dá alààyè kẹta+ ní ojú bíi ti èèyàn, ẹ̀dá alààyè kẹrin+ sì dà bí ẹyẹ idì tó ń fò.+
10 Bí ojú wọn ṣe rí nìyí: Ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ní ojú èèyàn, ojú kìnnìún+ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀tún, ojú akọ màlúù+ lẹ́gbẹ̀ẹ́ òsì, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn sì ní ojú+ idì.+
7 Ẹ̀dá alààyè àkọ́kọ́ dà bíi kìnnìún,+ ẹ̀dá alààyè kejì dà bí akọ ọmọ màlúù,+ ẹ̀dá alààyè kẹta+ ní ojú bíi ti èèyàn, ẹ̀dá alààyè kẹrin+ sì dà bí ẹyẹ idì tó ń fò.+