6 Àmọ́ ohun tí mo sọ àti àṣẹ tí mo pa fún àwọn ìránṣẹ́ mi, àwọn wòlíì, ó ṣẹ sí àwọn baba yín lára, àbí kò ṣẹ?’+ Torí náà, wọ́n pa dà sọ́dọ̀ mi, wọ́n sì sọ pé: ‘Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti fi ìyà jẹ wá nítorí àwọn ọ̀nà wa àti àwọn ìṣe wa, bó ṣe pinnu láti ṣe.’”+