Diutarónómì 32:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 torí pé ẹ̀yin méjèèjì kò jẹ́ olóòótọ́ sí mi láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, níbi omi Mẹ́ríbà+ ti Kádéṣì ní aginjù Síínì, torí pé ẹ ò fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ lójú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+
51 torí pé ẹ̀yin méjèèjì kò jẹ́ olóòótọ́ sí mi láàárín àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, níbi omi Mẹ́ríbà+ ti Kádéṣì ní aginjù Síínì, torí pé ẹ ò fi hàn pé mo jẹ́ mímọ́ lójú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+