Nọ́ńbà 25:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń gbé ní Ṣítímù,+ wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í bá àwọn ọmọbìnrin Móábù+ ṣe ìṣekúṣe. Diutarónómì 9:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nígbà tí Jèhófà ní kí ẹ lọ láti Kadeṣi-bánéà,+ tó sì sọ pé, ‘Ẹ gòkè lọ gba ilẹ̀ tó dájú pé màá fún yín!’ ẹ tún ṣe ohun tó lòdì sí àṣẹ tí Jèhófà Ọlọ́run yín pa,+ ẹ ò gbà á gbọ́,+ ẹ ò sì ṣègbọràn sí i.
25 Nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń gbé ní Ṣítímù,+ wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í bá àwọn ọmọbìnrin Móábù+ ṣe ìṣekúṣe.
23 Nígbà tí Jèhófà ní kí ẹ lọ láti Kadeṣi-bánéà,+ tó sì sọ pé, ‘Ẹ gòkè lọ gba ilẹ̀ tó dájú pé màá fún yín!’ ẹ tún ṣe ohun tó lòdì sí àṣẹ tí Jèhófà Ọlọ́run yín pa,+ ẹ ò gbà á gbọ́,+ ẹ ò sì ṣègbọràn sí i.