2 Kíróníkà 7:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 ńṣe ni màá fa Ísírẹ́lì tu lórí ilẹ̀ mi tí mo fún wọn,+ màá gbé ilé yìí tí mo yà sí mímọ́ fún orúkọ mi sọ nù kúrò níwájú mi, màá sọ ọ́ di ohun ẹ̀gàn* àti ohun ẹ̀sín láàárín gbogbo èèyàn.+ Ìdárò 2:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jèhófà ti ṣe ohun tó ní lọ́kàn;+ ó ti ṣe ohun tó sọ,+Ohun tó ti pa láṣẹ tipẹ́tipẹ́.+ Ó ti ya ọ́ lulẹ̀, kò sì ṣàánú rẹ.+ Ó ti mú kí ọ̀tá yọ̀ lórí rẹ; ó ti mú kí agbára* àwọn elénìní rẹ borí.
20 ńṣe ni màá fa Ísírẹ́lì tu lórí ilẹ̀ mi tí mo fún wọn,+ màá gbé ilé yìí tí mo yà sí mímọ́ fún orúkọ mi sọ nù kúrò níwájú mi, màá sọ ọ́ di ohun ẹ̀gàn* àti ohun ẹ̀sín láàárín gbogbo èèyàn.+
17 Jèhófà ti ṣe ohun tó ní lọ́kàn;+ ó ti ṣe ohun tó sọ,+Ohun tó ti pa láṣẹ tipẹ́tipẹ́.+ Ó ti ya ọ́ lulẹ̀, kò sì ṣàánú rẹ.+ Ó ti mú kí ọ̀tá yọ̀ lórí rẹ; ó ti mú kí agbára* àwọn elénìní rẹ borí.