ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 49:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 “‘Nítorí náà, wò ó! ọjọ́ ń bọ̀,’ ni Jèhófà wí,

      ‘Tí màá mú kí a gbọ́ ìró ogun* ní Rábà+ àwọn ọmọ Ámónì.+

      Ó máa di àwókù,

      Wọ́n á sì dáná sun àwọn àrọko* rẹ̀.’

      ‘Ísírẹ́lì á sì sọ àwọn tó gba tọwọ́ rẹ̀ di ohun ìní,’+ ni Jèhófà wí.

  • Ìsíkíẹ́lì 25:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Èmi yóò sọ Rábà+ di ibi tí àwọn ràkúnmí á ti máa jẹko, èmi yóò sì sọ ilẹ̀ àwọn ọmọ Ámónì di ibi ìsinmi agbo ẹran; ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.”’”

  • Émọ́sì 1:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Torí náà, màá sọ iná sí ògiri Rábà,+

      Á sì jó àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò run,

      Ariwo á sọ ní ọjọ́ ogun,

      Àti ìjì líle ní ọjọ́ ẹ̀fúùfù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́