Jeremáyà 21:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “‘“Nítorí mo ti dojú mi kọ ìlú yìí láti mú àjálù bá a, kì í ṣe fún ire,”+ ni Jèhófà wí. “Màá fi lé ọba Bábílónì lọ́wọ́,+ á sì dáná sun ún.”+ Jeremáyà 32:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Àwọn ará Kálídíà tó ń bá ìlú yìí jà máa wọlé wá, wọ́n á sọ iná sí i, wọ́n á sì sun ún kanlẹ̀+ pẹ̀lú àwọn ilé tí àwọn èèyàn náà ti ń rú ẹbọ lórí òrùlé wọn sí Báálì, tí wọ́n sì ti ń da ọrẹ ohun mímu sí àwọn ọlọ́run míì láti mú mi bínú.’+ Ìsíkíẹ́lì 22:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Èmi yóò fọ́n ọ ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè, èmi yóò tú ọ ká sí àwọn ilẹ̀,+ màá sì fòpin sí ìwà àìmọ́ rẹ.+
10 “‘“Nítorí mo ti dojú mi kọ ìlú yìí láti mú àjálù bá a, kì í ṣe fún ire,”+ ni Jèhófà wí. “Màá fi lé ọba Bábílónì lọ́wọ́,+ á sì dáná sun ún.”+
29 Àwọn ará Kálídíà tó ń bá ìlú yìí jà máa wọlé wá, wọ́n á sọ iná sí i, wọ́n á sì sun ún kanlẹ̀+ pẹ̀lú àwọn ilé tí àwọn èèyàn náà ti ń rú ẹbọ lórí òrùlé wọn sí Báálì, tí wọ́n sì ti ń da ọrẹ ohun mímu sí àwọn ọlọ́run míì láti mú mi bínú.’+
15 Èmi yóò fọ́n ọ ká sáàárín àwọn orílẹ̀-èdè, èmi yóò tú ọ ká sí àwọn ilẹ̀,+ màá sì fòpin sí ìwà àìmọ́ rẹ.+