-
Ìsíkíẹ́lì 33:14, 15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “‘Tí mo bá sì sọ fún ẹni burúkú pé: “Ó dájú pé wàá kú,” tó wá fi ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ sílẹ̀, tó sì ń ṣe ohun tó tọ́ àti ohun tó jẹ́ òdodo,+ 15 tí ẹni burúkú náà wá dá ohun tí wọ́n fi ṣe ìdúró pa dà,+ tó dá àwọn nǹkan tó jí pa dà,+ tó ń hùwà tó dáa láti fi hàn pé òun ń tẹ̀ lé àṣẹ tó ń fúnni ní ìyè, ó dájú pé yóò máa wà láàyè.+ Kò ní kú.
-