Jẹ́nẹ́sísì 10:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Kénáánì bí Sídónì+ àkọ́bí rẹ̀ àti Hétì+ Jẹ́nẹ́sísì 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 àwọn Áfádì,+ àwọn Sémárì àti àwọn Hámátì.+ Lẹ́yìn náà, àwọn ìdílé àwọn ọmọ Kénáánì tàn káàkiri.