Àìsáyà 23:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ìkéde nípa Tírè:+ Ẹ pohùn réré ẹkún, ẹ̀yin ọkọ̀ òkun Táṣíṣì!+ Torí a ti run èbúté; kò ṣeé wọ̀. A ti ṣi í payá fún wọn láti ilẹ̀ Kítímù.+ Àìsáyà 23:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọkà* Ṣíhórì*+ gba orí omi púpọ̀,Ìkórè Náílì, owó tó ń wọlé fún un,Tó ń mú èrè wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+ Ìsíkíẹ́lì 27:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “‘“Táṣíṣì+ bá ọ dòwò pọ̀ torí ọrọ̀ rẹ pọ̀ rẹpẹtẹ.+ Fàdákà, irin, tánganran àti òjé ni wọ́n fi ṣe pàṣípààrọ̀ ọjà lọ́dọ̀ rẹ.+
23 Ìkéde nípa Tírè:+ Ẹ pohùn réré ẹkún, ẹ̀yin ọkọ̀ òkun Táṣíṣì!+ Torí a ti run èbúté; kò ṣeé wọ̀. A ti ṣi í payá fún wọn láti ilẹ̀ Kítímù.+
3 Ọkà* Ṣíhórì*+ gba orí omi púpọ̀,Ìkórè Náílì, owó tó ń wọlé fún un,Tó ń mú èrè wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+
12 “‘“Táṣíṣì+ bá ọ dòwò pọ̀ torí ọrọ̀ rẹ pọ̀ rẹpẹtẹ.+ Fàdákà, irin, tánganran àti òjé ni wọ́n fi ṣe pàṣípààrọ̀ ọjà lọ́dọ̀ rẹ.+