Jeremáyà 6:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Mo sì yan àwọn olùṣọ́+ tí wọ́n sọ pé,‘Ẹ fetí sí ìró ìwo!’”+ Àmọ́ wọ́n sọ pé: “A ò ní fetí sí i.”+ Sekaráyà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “‘Ẹ má dà bí àwọn baba yín, tí àwọn wòlíì àtijọ́ kéde fún pé: “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Ẹ jọ̀ọ́, ẹ fi ìwà búburú yín sílẹ̀* kí ẹ sì jáwọ́ nínú iṣẹ́ ibi.’”’+ “‘Àmọ́ wọn ò gbọ́, wọn ò sì fetí sí ohun tí mo sọ,’+ ni Jèhófà wí.
17 “Mo sì yan àwọn olùṣọ́+ tí wọ́n sọ pé,‘Ẹ fetí sí ìró ìwo!’”+ Àmọ́ wọ́n sọ pé: “A ò ní fetí sí i.”+
4 “‘Ẹ má dà bí àwọn baba yín, tí àwọn wòlíì àtijọ́ kéde fún pé: “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Ẹ jọ̀ọ́, ẹ fi ìwà búburú yín sílẹ̀* kí ẹ sì jáwọ́ nínú iṣẹ́ ibi.’”’+ “‘Àmọ́ wọn ò gbọ́, wọn ò sì fetí sí ohun tí mo sọ,’+ ni Jèhófà wí.