-
Àìsáyà 21:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 A ti sọ ìran kan tó le fún mi:
Ọ̀dàlẹ̀ ń dalẹ̀,
Apanirun sì ń pani run.
Gòkè lọ, ìwọ Élámù! Gbógun tini, ìwọ Mídíà!+
Màá fòpin sí gbogbo ẹ̀dùn ọkàn tó mú kó bá àwọn èèyàn.+
3 Ìdí nìyẹn tí mo fi ń jẹ̀rora gidigidi.*+
Àwọn iṣan mi ń sún kì,
Bíi ti obìnrin tó ń bímọ.
Ìdààmú tó bá mi ò jẹ́ kí n gbọ́ràn;
Ìyọlẹ́nu tó bá mi ò jẹ́ kí n ríran.
-