7 Àgbà òṣìṣẹ́ láàfin sì fún wọn ní orúkọ;* ó pe Dáníẹ́lì ní Bẹtiṣásárì,+ ó pe Hananáyà ní Ṣádírákì, ó pe Míṣáẹ́lì ní Méṣákì, ó sì pe Asaráyà ní Àbẹ́dínígò.+
8 Nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín, Dáníẹ́lì wá síwájú mi, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Bẹtiṣásárì,+ látinú orúkọ ọlọ́run mi,+ ẹni tí ẹ̀mí àwọn ọlọ́run mímọ́ + wà nínú rẹ̀, mo sì rọ́ àlá náà fún un: