Àìsáyà 13:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Màá gbé àwọn ará Mídíà dìde sí wọn,+Àwọn tí kò ka fàdákà sí nǹkan kan,Tí wúrà ò sì já mọ́ nǹkan kan lójú wọn. 18 Ọfà wọn máa run àwọn ọ̀dọ́kùnrin túútúú;+Wọn ò ní káàánú èso ikùn,Wọn ò sì ní ṣàánú àwọn ọmọdé. Dáníẹ́lì 11:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Òótọ́ ni ohun tí mo fẹ́ sọ fún ọ báyìí: “Wò ó! Ọba mẹ́ta míì máa dìde fún Páṣíà, ìkẹrin máa kó ọrọ̀ tó pọ̀ jọ ju ti gbogbo àwọn yòókù lọ. Tí ọrọ̀ rẹ̀ bá sì ti mú kó di alágbára, ó máa gbé ohun gbogbo dìde sí ìjọba ilẹ̀ Gíríìsì.+
17 Màá gbé àwọn ará Mídíà dìde sí wọn,+Àwọn tí kò ka fàdákà sí nǹkan kan,Tí wúrà ò sì já mọ́ nǹkan kan lójú wọn. 18 Ọfà wọn máa run àwọn ọ̀dọ́kùnrin túútúú;+Wọn ò ní káàánú èso ikùn,Wọn ò sì ní ṣàánú àwọn ọmọdé.
2 Òótọ́ ni ohun tí mo fẹ́ sọ fún ọ báyìí: “Wò ó! Ọba mẹ́ta míì máa dìde fún Páṣíà, ìkẹrin máa kó ọrọ̀ tó pọ̀ jọ ju ti gbogbo àwọn yòókù lọ. Tí ọrọ̀ rẹ̀ bá sì ti mú kó di alágbára, ó máa gbé ohun gbogbo dìde sí ìjọba ilẹ̀ Gíríìsì.+