Diutarónómì 9:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí náà, kí o mọ̀ lónìí pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa sọdá ṣáájú rẹ.+ Ó jẹ́ iná tó ń jóni run,+ ó sì máa pa wọ́n run. Ó máa tẹ̀ wọ́n lórí ba níṣojú yín kí ẹ lè tètè lé wọn jáde,* kí ẹ sì pa wọ́n run, bí Jèhófà ṣe ṣèlérí fún ọ.+ Hébérù 12:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Torí Ọlọ́run wa jẹ́ iná tó ń jóni run.+
3 Torí náà, kí o mọ̀ lónìí pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa sọdá ṣáájú rẹ.+ Ó jẹ́ iná tó ń jóni run,+ ó sì máa pa wọ́n run. Ó máa tẹ̀ wọ́n lórí ba níṣojú yín kí ẹ lè tètè lé wọn jáde,* kí ẹ sì pa wọ́n run, bí Jèhófà ṣe ṣèlérí fún ọ.+