ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 26:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ẹ lọ, ẹ̀yin èèyàn mi, ẹ wọnú yàrá yín tó wà ní inú,

      Kí ẹ sì ti àwọn ilẹ̀kùn yín mọ́ ara yín.+

      Ẹ fi ara yín pa mọ́ fúngbà díẹ̀,

      Títí ìbínú* náà fi máa kọjá lọ.+

  • Jóẹ́lì 2:31, 32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Oòrùn yóò ṣókùnkùn, òṣùpá yóò sì di ẹ̀jẹ̀+

      Kí ọjọ́ ńlá Jèhófà tó ń bani lẹ́rù tó dé.+

      32 Gbogbo ẹni tó bá ń ké pe orúkọ Jèhófà yóò sì rí ìgbàlà;+

      Torí àwọn tó sá àsálà yóò wà ní Òkè Síónì àti ní Jerúsálẹ́mù+ bí Jèhófà ṣe sọ,

      Àwọn tó là á já tí Jèhófà pè.”

  • Mátíù 24:21, 22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 torí ìpọ́njú ńlá máa wà nígbà náà,+ irú èyí tí kò tíì ṣẹlẹ̀ rí láti ìbẹ̀rẹ̀ ayé títí di báyìí, àní, irú rẹ̀ kò ní ṣẹlẹ̀ mọ́.+ 22 Kódà, ẹran ara kankan ò ní là á já, àfi tí a bá dín àwọn ọjọ́ yẹn kù; àmọ́ nítorí àwọn àyànfẹ́, a máa dín àwọn ọjọ́ yẹn kù.+

  • Ìfihàn 7:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ọ̀kan nínú àwọn àgbààgbà náà dáhùn, ó bi mí pé: “Àwọn wo ni àwọn tó wọ aṣọ funfun yìí,+ ibo ni wọ́n sì ti wá?” 14 Mo sọ fún un lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ pé: “Olúwa mi, ìwọ lo mọ̀ ọ́n.” Ó wá sọ fún mi pé: “Àwọn yìí ni àwọn tó wá látinú ìpọ́njú ńlá náà,+ wọ́n ti fọ aṣọ wọn, wọ́n sì ti sọ wọ́n di funfun nínú ẹ̀jẹ̀ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́