Àìsáyà 45:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ohun tí Jèhófà sọ fún ẹni tó yàn nìyí, fún Kírúsì,+Ẹni tí mo di ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú,+Láti tẹ àwọn orílẹ̀-èdè lórí ba níwájú rẹ̀,+Láti gba ohun ìjà* àwọn ọba,Láti ṣí àwọn ilẹ̀kùn aláwẹ́ méjì níwájú rẹ̀,Kí wọ́n má sì ti àwọn ẹnubodè: Jeremáyà 51:28, 29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ẹ yan àwọn orílẹ̀-èdè* lé e lórí,Àwọn ọba Mídíà,+ àwọn gómìnà rẹ̀ àti gbogbo àwọn ìjòyè rẹ̀Àti gbogbo ilẹ̀ tí wọ́n ń ṣàkóso lé lórí. 29 Ilẹ̀ ayé á mì tìtì, jìnnìjìnnì á sì bá a,Nítorí pé èrò Jèhófà sí Bábílónì máa ṣẹ Láti sọ ilẹ̀ Bábílónì di ohun àríbẹ̀rù, tí ẹnì kánkán kò ní gbé ibẹ̀.+ Dáníẹ́lì 5:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 “PÉRÉSÌ, a ti pín ìjọba rẹ, a sì ti fún àwọn ará Mídíà àti Páṣíà.”+
45 Ohun tí Jèhófà sọ fún ẹni tó yàn nìyí, fún Kírúsì,+Ẹni tí mo di ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú,+Láti tẹ àwọn orílẹ̀-èdè lórí ba níwájú rẹ̀,+Láti gba ohun ìjà* àwọn ọba,Láti ṣí àwọn ilẹ̀kùn aláwẹ́ méjì níwájú rẹ̀,Kí wọ́n má sì ti àwọn ẹnubodè:
28 Ẹ yan àwọn orílẹ̀-èdè* lé e lórí,Àwọn ọba Mídíà,+ àwọn gómìnà rẹ̀ àti gbogbo àwọn ìjòyè rẹ̀Àti gbogbo ilẹ̀ tí wọ́n ń ṣàkóso lé lórí. 29 Ilẹ̀ ayé á mì tìtì, jìnnìjìnnì á sì bá a,Nítorí pé èrò Jèhófà sí Bábílónì máa ṣẹ Láti sọ ilẹ̀ Bábílónì di ohun àríbẹ̀rù, tí ẹnì kánkán kò ní gbé ibẹ̀.+