-
1 Àwọn Ọba 16:30-32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Ìwà Áhábù ọmọ Ómírì tún wá burú lójú Jèhófà ju ti gbogbo àwọn tí ó wà ṣáájú rẹ̀.+ 31 Àfi bíi pé nǹkan kékeré ni lójú rẹ̀ bó ṣe ń rìn nínú ẹ̀ṣẹ̀ Jèróbóámù+ ọmọ Nébátì, ó tún fẹ́ Jésíbẹ́lì+ ọmọ Etibáálì, ọba àwọn ọmọ Sídónì,+ ó bẹ̀rẹ̀ sí í sin Báálì,+ ó sì ń forí balẹ̀ fún un. 32 Yàtọ̀ síyẹn, ó mọ pẹpẹ kan fún Báálì ní ilé* Báálì+ tí ó kọ́ sí Samáríà.
-
-
2 Àwọn Ọba 10:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Bí Jéhù ṣe pa Báálì rẹ́ ní Ísírẹ́lì nìyẹn.
-