Àìsáyà 24:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Òṣùpá àrànmọ́jú máa tẹ́,Ojú sì máa ti oòrùn tó ń ràn,+Torí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti di Ọba+ ní Òkè Síónì+ àti ní Jerúsálẹ́mù,Ògo rẹ̀ ń tàn níwájú àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn rẹ̀.*+ Míkà 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Èmi yóò mú kí ẹni* tó ń tiro ṣẹ́ kù,+Èmi yóò sì sọ ẹni tí wọ́n ti mú lọ sí ọ̀nà tó jìn di orílẹ̀-èdè alágbára;+Jèhófà yóò sì jọba lé wọn lórí ní Òkè Síónì,Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé.
23 Òṣùpá àrànmọ́jú máa tẹ́,Ojú sì máa ti oòrùn tó ń ràn,+Torí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ti di Ọba+ ní Òkè Síónì+ àti ní Jerúsálẹ́mù,Ògo rẹ̀ ń tàn níwájú àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn rẹ̀.*+
7 Èmi yóò mú kí ẹni* tó ń tiro ṣẹ́ kù,+Èmi yóò sì sọ ẹni tí wọ́n ti mú lọ sí ọ̀nà tó jìn di orílẹ̀-èdè alágbára;+Jèhófà yóò sì jọba lé wọn lórí ní Òkè Síónì,Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé.