1 Àwọn Ọba 12:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ìgbà náà ni ó gbé ọ̀kan sí Bẹ́tẹ́lì,+ ó sì gbé ìkejì sí Dánì.+ 1 Àwọn Ọba 12:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Jèróbóámù tún dá àjọyọ̀ kan sílẹ̀ ní oṣù kẹjọ, ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù náà, bí àjọyọ̀ tó wà ní Júdà.+ Ó rú ẹbọ sí àwọn ère ọmọ màlúù tó ṣe sórí àwọn pẹpẹ tó ṣe ní Bẹ́tẹ́lì,+ ó sì yan àwọn àlùfáà ní Bẹ́tẹ́lì fún àwọn ibi gíga tó ṣe. 1 Àwọn Ọba 13:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Èèyàn Ọlọ́run+ kan wá láti Júdà sí Bẹ́tẹ́lì bí Jèhófà ṣe pàṣẹ fún un, nígbà tí Jèróbóámù dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ+ láti mú ẹbọ rú èéfín.
32 Jèróbóámù tún dá àjọyọ̀ kan sílẹ̀ ní oṣù kẹjọ, ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù náà, bí àjọyọ̀ tó wà ní Júdà.+ Ó rú ẹbọ sí àwọn ère ọmọ màlúù tó ṣe sórí àwọn pẹpẹ tó ṣe ní Bẹ́tẹ́lì,+ ó sì yan àwọn àlùfáà ní Bẹ́tẹ́lì fún àwọn ibi gíga tó ṣe.
13 Èèyàn Ọlọ́run+ kan wá láti Júdà sí Bẹ́tẹ́lì bí Jèhófà ṣe pàṣẹ fún un, nígbà tí Jèróbóámù dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ+ láti mú ẹbọ rú èéfín.